Font Size
Lefitiku 12:3
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Lefitiku 12:3
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
3 (A)Ní ọjọ́ kẹjọ ni kí ẹ kọ ọmọ náà ní ilà.
Read full chapter
Gẹnẹsisi 17:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Gẹnẹsisi 17:10
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
10 (A)Èyí ni májẹ̀mú mi pẹ̀lú rẹ àti ìran rẹ lẹ́yìn rẹ, májẹ̀mú tí ẹ̀yin yóò máa pamọ́. Gbogbo ọkùnrin yín ni a gbọdọ̀ kọ ní ilà.
Read full chapter
Gẹnẹsisi 21:4
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Gẹnẹsisi 21:4
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
4 (A)Nígbà tí Isaaki pé ọmọ ọjọ́ mẹ́jọ, Abrahamu sì kọ ọ́ ní ilà gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run ti pàṣẹ fún un.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.