Font Size
Matiu 24:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 24:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
31 Yóò sì rán àwọn angẹli rẹ̀ jáde pẹ̀lú ohùn ìpè ńlá, wọn yóò sì kó gbogbo àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ láti orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé àti ọ̀run jọ.
Read full chapter
1 Kọrinti 15:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 15:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
23 (A)Ṣùgbọ́n olúkúlùkù ènìyàn ní ipá tirẹ̀: Kristi àkọ́bí; lẹ́yìn èyí àwọn tí ó jẹ́ tí Kristi ni wíwá rẹ̀.
Read full chapter
2 Tẹsalonika 2:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
2 Tẹsalonika 2:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ọkùnrin aláìlófin náà
2 (A)Ní ti bíbọ̀ Jesu Kristi Olúwa wa, àti ti ìpéjọ wa sọ́dọ̀ rẹ̀, àwa wí fún yín ará,
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.